Song picture
Iranlowo
Comment Share
License   $0.00
Free download
Iranlowo by Hibeekay is a reggae styled inspirational song that talks about the need of divine help
iranlowo
Commercial uses of this track are allowed.
Adaptations of this track are allowed to be shared, as long as licensee shares alike.
You must attribute the work in the manner specified by the artist.
Artist picture
Awoyomi Oluwabukunmi Abraham
I'm Awoyomi Oluwabukunmi Abraham... I'm from Iloko Ijesa, Osun state but I was born and brought up in Ibadan... I attended Success Group of Schools at orita challenge, Ibadan for my Nursery, Primary and Secondary Education. Then I had my first degree in Demography and Social Statistics at Federal University Oye Ekiti.
Song Info
Genre
R&B Gospel
Charts
Peak #76
Peak in subgenre #6
Author
Awoyomi Abraham Oluwabukunmi
Rights
2025
Uploaded
January 20, 2025
Track Files
MP3
MP3 7.5 MB 160 kbps 6:04
Lyrics
#VERSE Oluwa ni imole mi Ati igbala mi tani emi yo beru Agbara emi mi Aya tani yo fo mi Okan mi bale Tori mori Oluwa ti mo gbojule Oun ni yio gbemileke Tori mi o le da se Lai si iranlowo re Oluwa iwo ni Mo gbe okan mi Soke si o Olorun mi Ma je koju ko ti mi Baba mo duro ti o Baba fona re han mi Ki o si ko mi Kin le je eso anu re Toripe kosi ona miran Lati se yege Lai si iranlowo re #CHORUS Iranlowo Ibukun Oluwa lo n mu ni la Itoju Oluwa lo n wo ni san Itoni Oluwa lo n mu ni gbon Baba ran mi lowo Jesu Oluwa lowo soro mi Owo re ma lo n gbe ni ro Anu re lo n mu ni sogo Baba ran mi lowo #VERSE Emi yo gboju mi sori oke wonni Nibo iranlowo mi yio ti wa Iranlowo mi yio towo Oluwa wa Ti o da orun oun aye Oba ayeraye Oun ki yo je ki ese mi ko ye Nitori oun ni Olupamo mi Mo se ni Alewilese Aleselewi Baba Awimayehum Ni mo se so wipe se Oluwa iwo ni Mo gbe okan mi Soke si o Olorun mi Ma je koju ko ti mi Baba mo duro ti o Baba fona re han mi Ki o si ko mi Kin le je eso anu re Toripe kosi ona miran Lati se yege Lai si iranlowo re #CHORUS Iranlowo Ibukun Oluwa lo n mu ni la Itoju Oluwa lo n wo ni san Itoni Oluwa lo n mu ni gbon Baba ran mi lowo Jesu Oluwa lowo soro mi Owo re ma lo n gbe ni ro Anu re lo n mu ni sogo Baba ran mi lowo #Bridge Ni mo se so wipe se Iranlowo Ase Oluwa lo n gbe ni leke Oro Oluwa lo n gba ni la Abo Oluwa lo n pa ni mo Baba ran mi lowo Jesu Oluwa da si oro mi Tori, Idasi re ma n niyanju Ohun lo n fun mi ni idunu Baba ran mi lowo Ni mo se so pe Oro re lo n gba ni la Anu re lo n mu ni sogo (Baba ran mi lowo) Ibukun re lo n mu ni la Owo re lo n mu ni ro (Baba ran mi lowo) Itoju re lo n wo ni san Itoni re lo n mu ni gbon (Baba ran mi lowo) Oya so pe iranlowo se #CHORUS Iranlowo Ibukun Oluwa lo n mu ni la Itoju Oluwa lo n wo ni san Itoni Oluwa lo n mu ni gbon Baba ran mi lowo Jesu Oluwa lowo soro mi Owo re ma lo n gbe ni ro Anu re lo n mu ni sogo Baba ran mi lowo
Comments
Please sign up or log in to post a comment.