Song picture
Agogo ati Shekere
Play
Pause
Comment Share
License   $0.00
Free download
Agogo ati Shekere by Hibeekay is a yoruba indigenous song directing the psalmists to praise the Lord aligning with the book of Psalms
Creative Commons license
Commercial uses of this track are allowed
Adaptations of this track are allowed to be shared, as long as licensee shares alike
You must attribute the work in the manner specified by the artist
Charts
Peak #65
Peak in subgenre #9
Author
Awoyomi Abraham Oluwabukunmi
Rights
2024
Uploaded
July 17, 2024
MP3
MP3 6.6 MB, 160 kbps, 4:53
Meta Data
Beat
4/4
Key
F maj
Character
Positivity
dark, sad, angry
happy
Appeal
unique
radio-friendly
Lyrics
#Chorus Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo #Instrumental #Verse E korin titun s'Oluwa Nitori to ti se ohun iyanu Jeki okun ko ma ho pelu ikun re Je ki odo ko ma sape k'oke ma sajoyo E fope f'Oluwa (O seun) Anu re duro lailai (O seun) O fi ogbon da orun (O seun) O te ile lori omi (O seun) O da awon imole nla (O seun) Orun lati joba osan (O seun) Osupa ati irawo joba oru (O seun) E ba mi f'ope f'Olorun ehh #Chorus Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo #Verse Moniwipe E lo si enu ona re teyin tope Ati si agbala re teyin tiyin E dupe e f'ibukun fun oruko re Nitori to po lore anu re konipekun Eniti o ranti wa (O seun) Ninu iwa irele wa (O seun) Anu re duro lailai (O seun) O da wa nde lowo ota (O seun) O fi ounje fun gbogbo eda (O seun) O sise iyanu nla (O seun) Jeki gbogbo ohun to lemi (O seun) Ko fiyin f'Oluwa Oba awon oba #Chorus Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo #Instrumental #Chorus Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Efi duru korin si Oluwa Oba mimo F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Community
Comment
Please sign up or log in to post a comment.