Song picture
Anu
Play
Pause
Comment Share
Free download
Anu by Hibeekay is a gospel track focusing on the importance and the need for God's mercy in one's life and endeavours... Experience God's mercy in your life as you download, listen and share
Charts
Peak #23
Peak in subgenre #3
Author
Hibeekay
Rights
Hibeekay
Uploaded
May 31, 2022
MP3
MP3 7.5 MB, 160 kbps, 6:30
Story behind the song
Anu by Hibeekay is a gospel track focusing on the importance and the need for God's mercy in one's life and endeavours... Experience God's mercy in your life as you download, listen and share
Lyrics
Anu Lead: Baba sanu mi Ranmilowo Oluwa Jeki Orun si fun mi Kanu soro laye mi All: Baba sanu mi Ranmilowo Oluwa Jeki Orun si fun mi Kanu soro laye mi Lead: Baba sanu mi Ranmilowo Oluwa Jeki Orun si fun mi Kanu soro laye mi All: Baba sanu mi Ranmilowo Oluwa Jeki Orun si fun mi Kanu soro laye mi Lead: Kosi ohun ti mo le se Lai si iranlowo re baba Ayeraye ma wo mi niran jowo dasi oro aye mi Ki anu re fohun ki gbogbo idawole mi ma yori si rere Bi orun ba si fun mi Ase irorun ohun lo ma tele Adura a ma gba alubarika a wole ise a mu ere wa Ire lotun ire losi laye eyan orin ope a tun yo All: Baba sanu mi Ranmilowo Oluwa Jeki Orun si fun mi Kanu soro laye mi Lead: Oro re fi yewa, iwo yio sanu fun eniti iwo o sanu fun Eyonu re yio wa lori eniti iwo ba yonu si laye ati ni orun Baba jowo je n nipin ninu eyonu re Kin se nipa adura, abi iwa mimo abi eto bikose nipa ore ofe ati orire Aye mi nilo ore ofe ati orire lati odo re baba mi Kanu re joba laye mi ati ohun gbogbo to jemo temi Chorus: Baba sanu mi Ranmilowo Oluwa Jeki Orun si fun mi Kanu soro laye mi Lead: Silekun ayo mi Baba silekun ayo mi Ibanuje o, jeko jina silemi Wa mu inu mi dun, Baba onile ayo Oro ayo mi, ma jeko pamilekun All: Silekun ayo mi Baba silekun ayo mi Ibanuje o, jeko jina silemi Wa mu inu mi dun, Baba onile ayo Oro ayo mi, ma jeko pamilekun Silekun ayo mi Baba silekun ayo mi Ibanuje o, jeko jina silemi Wa mu inu mi dun, Baba onile ayo Oro ayo mi, ma jeko pamilekun All: Baba sanu mi Ranmilowo Oluwa Jeki Orun si fun mi Kanu soro laye mi (Till fade)
Community
Appears on
Comment
Please sign up or log in to post a comment.